Download + Lyrics: E Yin Oluwa Halleluyah – Tope Alabi
Tope Alabi shares the lyrics of “E Yin Oluwa Halleluyah” from her latest album “Hymnal” Vol. 1 produced by Dekunle Oniyo.
The 8-track album which she released recently feature popular Yoruba hymnals used for praising and worshipping God.
Lyrics: E Yin Oluwa Halleluyah By Tope Alabi
Verse 1:
Eje ka f’ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai
Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah
Verse 2:
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun
Verse 3:
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo
Verse 4:
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo
STREAM HERE:
