LyricsNigeria Gospel MusicTope Alabi SongsYoruba Gospel Music

[Hymnal + Lyrics] Lae La O Ma Bo Oluwa – Tope Alabi

Download + Lyrics: Lae La O Ma Bo Oluwa – Tope Alabi

Indigenous gospel music minister, Tope Alabi shares the lyrics of “Lae La O Ma Bo Oluwa” from her newest “Hymnal” Vol. 1 Album produced by Dekunle Oniyo.

The 8-track album which she released recently feature popular Yoruba hymnals used for praising and worshipping God.

DOWNLOAD HYMNAL ALBUM HERE

Share with colleagues.

Comment on this post below.

Lyrics: Lae La O Ma Bo Oluwa By Tope Alabi

Verse 1:
Nitori iwo je oluwa, lae la oma bo o
Nitori iwo ni oluwa, lae la oma bo o
A o pelu a o pelu a o pelu angeli bo o
A o pelu a o pelu a o pelu awon eniyan bo o

Chorus:
A o pelu a o pelu a o pelu angeli bo o
A o pelu a o pelu a o pelu awon eniyan bo o

Verse 2:
Ogangan oju awon angeli, lae la oma bo o
Imole tomo orun ja aye, lae la oma bo o
Ogunwa ninu imole ara re, lae la oma bo o
Akoso aye ateda gbogbo, lae la oma bo o
Imole re oluwa duro lailai, lae la oma bo o

Verse 3:
Oju ogo re nko monomono, lae la oma bo o
Imole orun dan itanshan, lae la oma bo o
Si iwo ti oruko re yio wa titi lai, lae la oma bo o
Ogo re titi de opin imole orun, lae la oma bo o
Ogo toji oku ojo kerin dide o, lae la oma bo o

Verse 4:
Si iwo eni mimo israeli, lae la oma bo o
Si iwo ti yio ku nigbati aye batan, lae la oma bo o
Ibujoko eniti idajo gbogbo wa, lae la oma bo o
Ogo t’awon ti ara pada yio ri lojukoju, lae la oma bo o
Si iwo ogo ibere ti o lopin, lae la oma bo o

Ref:
Lae la o ma bo o, lae la o ma gbe o ga
Lae la o ma bo o, kabiesi o oba
Lae la o ma bo o, lae la o ma gbe o ga
Lae la o ma bo o, kabiesi o oba

STREAM HERE:

the authorAmenRadio
Ethical journalists and We specialize in the gospel media, studied the ropes of Broadcasting, Copy writing, Script writing, Voice Over Artiste. Internet Radio Broadcasting guru and decent sound engineers. Guess What? Its fun having you visiting AmenRadio Website. We appreciate your financial support.

Leave a Reply

Exit mobile version