LyricsNigeria Gospel MusicTope Alabi SongsYoruba Gospel Music

[Hymnal + Lyrics] L’oro L’ero Ati Ni’se – Tope Alabi

L’oro L’ero Ati Ni’se - Tope Alabi

L’oro L’ero Ati Ni’se - Tope Alabi

Download + Lyrics: L’oro L’ero Ati Ni’se – Tope Alabi

Yoruba gospel music minister, Tope Alabi shares the lyrics of “L’oro L’ero Ati Ni’se” from her newest “Hymnal” Vol. 1 Album produced by Dekunle Oniyo.

The 8-track album which she released recently feature popular Yoruba hymnals used for praising and worshipping God.

DOWNLOAD HYMNAL ALBUM HERE

Share with colleagues.

Comment on this post below.

Lyrics: L’oro L’ero Ati Ni’se By Tope Alabi

Verse 1:
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Chorus:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2:
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3:
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise.

STREAM HERE:

AmenRadio
the authorAmenRadio
Ethical journalists and We specialize in the gospel media, studied the ropes of Broadcasting, Copy writing, Script writing, Voice Over Artiste.Internet Radio Broadcasting guru and decent sound engineers.Guess What? Its fun having you visiting AmenRadio Website.We appreciate your financial support.

Leave a Reply