
Download + Lyrics: Aso Mi A Funfun Lau – Tope Alabi
Tope Alabi puts out the lyrics of “Aso Mi A Funfun Lau” from her latest album “Hymnal” Vol. 1.
The 8-track album which she released recently feature popular Yoruba hymnals used for praising and worshipping God.
The song and album is produced by Dekunle Oniyo.
Lyrics: Aso Mi A Funfun Lau By Tope Alabi
Chorus:
Aso mi a funfun lau lau lau
Aisedede mia kuro, ma funfun lau
Ese mi apere masi funfun
A o wemi lawemo o bi egbon owu
Verse 1:
Eni towa Ninu Jesu di eda tuntun
Ohun atijo oti koja lo
Ati wewa kuro ninu ese wa
A aso wa funfun lau lau lau
Verse 2:
Ka ronu piwada kako ese sile
Ka para wamo n’nu aisedede wa
ki emi mimo ko joba lokan wa
Angeli n yo tore’lese yipada
Verse 3:
Kosi ese ti Jesu kole wemo o
Anu re duro duro titi lailai
Elese ewa a o fisimi fokan re
Y’o we gbogbo re, y’o si funfun lau lau
Verse 4:
A’lanu lolorun, obe’lese wo bi omo ni
Kosi bese se le poto, alaforiji ni
Kiki da ko jewo, kaye re kogba sinmi
Chorus:
Aso mi a funfun lau lau lau
Aisedede mia kuro, ma funfun lau
Ese mi apere masi funfun
A o wemi lawemo o bi egbon owu
A o wemi lawemo o bi egbon owu
Call: A o we A o we A o we A o we
Res: A o wemi lawemo o bi egbon owu
Call: Gbogbo re gbogbo re gbogbo re gbogbo ese re
Res: A o wemi lawemo o bi egbon owu
STREAM HERE:

![Zion’s Hill - Tobi Olawale ft. Philipage [www.AmenRadio.net]](https://i0.wp.com/amenradio.net/wp-content/uploads/2026/08/Zions-Hill-Tobi-Olawale-ft.-Philipage-www.AmenRadio.net_.jpg?resize=272%2C170&ssl=1)




