Talented gospel music singer, Skat Praise issues a new song and lyrics “Igbala Ti De” produced By Octave while featuring popular gospel music veteran, Biyi Samuel.
The inspirational Yoruba titled track “Igbala Ti De” translates as “Salvation Has Come” in English language, follows Skat’s highly successful previous release, “Ife Iyebiye.”
The song is released in the ambience of the Christmas season.
Download, Listen and Share with colleagues.
Comment on this post below.
Lyrics: Igbala Ti De By Skat Praise feat. Biyi Samuel
Prelude:
Nitori a bi omo kunrin kan funwa.
Ijoba yio si wa ni ejika re
A o maa pe ni
Emmanueli
Intro:
Vocal 1:
Skat Praise
Eho eyo oooo, omo eniyan.
Itura de, Imole de o
Bina bawoleee okunkun a para daatibi Olugbala wa.
Chorus:
Atibi, atibi
Abi Olugbala kan funwa ooo
Iyee wole de (2x)
Interlude:
Vocal 2:
Biyi Samuel
Asiri orun oun aye, owa pelu eni toda orun oun aye.
Iye wa pelu Olorun ododo, igbala wa pelu Olugbala wa.
Oba to tele bi eni teni, ijinle leyin gbogbo itan.
Arugbo ojo, arugbo ojo alagbawi imole mii de.
Vocal 3:
Skat Praise:
Owa sayeee, kawa baa le yeee.
Bibi Olugbala iyaanu shaaa loje, ijoba bo lowo satani
Igbala tide fun gbogbo araye e
Chorus:
Atibi, atibi
Abi Olugbala kan funwa ooo
Iyee wole de (2x)
Interlude:
Bridge:
Skat Praise
Call – Otide o
Res – Igbala ti de
Call – Igbala tide sinu ayemi, ode sinu aye re, ode sorile ede Nigeria o.
Res – Igbala ti de
Call – Oun labani mule mama dani, ogbeja maseke ogbeja keru o bo nija
Res – Igbala ti de
Call – Oun loba toun foba je totun roba loye, oun logbemi soke to somi doge eee aaa.
Res – Igbala ti de
Ijoba tibo lowo satani aaati yege
Iye aye de oo, Olugbala de (2x)
Biyi Samuel
Call – Arugbo ojo tii de ooo
Res – Igbala ti de
Call – Kabiesi aponmo mo mo mo weyin arugbo ojo oo
Res – Igbala ti de
Call – Ijinle leyin gbogbo itan, gbanigbani lanilani kabiesi
Res – Igbala ti de
Call – Olugbala araye eee aduro tini nijo ogun le
Res – Igbala ti de
Call – Oke leyin onigbagbo o obiri ayi ayigba pada Igbala ti de
Res – Igbala ti de
Ijoba tibo lowo satani aaati yegeee, iye aye de o Olugbala de (2x)
Call – Olorun aposteli yi de o
Res – Igbala ti de
Call – Ogbeni nija keru o bonijaaa ee
Res – Igbala ti de
Call – Iwo shani ibere iwo shani ipari aatopin oo
Res – Igbala ti de
Ijoba ti bo lowo satani aaati yegeee iye aye de oo Olugbala de (2x)
Eeeeee
Iye ayeraye
Olugbala mi de o
Olugbala mi de
Oti de o
Ose kabiesi
Iye aye de
Igbala ti de







